Babalawo yoo so itan latinu ese Ifa, iru eni ti iru re ti sele si ri ati ohun ti o se si oro naa, yoo si so fun eni naa lati se bee gege. GBIGBE EDAN LO SILE AJEGBESE: Laye atijo eru jeje ni awon egbe ogboni je fun awon ara ilu nitori naa ti olowo ba loo fi ejo ajegbese to taku sun awon ogboni,awon ogboni yoo fi edan[amin ase ogboni]ran onise si ajegbese naa,itunmo eyi nip e ki ajegbese naa o maa bo wa si ile ogboni won a da si oro gbese naa,won a si pase fun ajegbese naa ki o san owo yii eru won nii mu ajegbese wa ona kiakia lati san gbese. Asa ijo jijo eyi ti o maa n suyo ninu tilu-tifon yala nibi ayeye isile, igbeyawo ati ikomojade tabi ni idi orisa Sango, Obatala, Orunmila ati bee bee lo se pataki. Gege bi owe Yoruba ti o wipe "ile la n wo, ki a to so omo loruko" A kii dede fun omo ni oruko ni ile Yoruba, ki won to fun omo loruko, won a se akiyesi iru ipo ti omo wa ni gba ti iya re bii tabi ipo ti ebi wa . EKA ISE: ASA. (A) awon oloja tita maa n pe de pe de oja (B) eran igbe kii po loja (C) imura awon eniyan kii dara to (D) kanga maa n lomi ninu (E) oorun asungbadun maa n wa. Ni ojo keji isinku; akara dindin naa ni yoo gba gbogbo ile oku kan. Ni ojo keta isinku abbl. E je oro aropo oruko [a] enikin-ni eyo opo,[b] enikeji eyo [d] enikeji opo. eni ti o ku toyuntoyun awon oloro nii se etutu sisin re. ABO:ni eni tabi ohun ti a se nnkan si, ap, EYAN; ni o maa n se afikun itunmo fun oro-oruko ap. Oro di pen-n-tuka. Se itupale asayan iwe ewi kin-in-ni ti ijoba yan. 700, 710, 720, 730, 740, 750, 760, 770,780, 790, 800, Mustapha Oyebamji (2006) EKO EDE ATI ASA YORUBA TITUN (S.S.S) University Press Oju iwe 12-15. It is believed the grandfather reincarnated. The child, whether male or female, born after the twins is called Idowu. oro ti o ba jeyo leyin yoo,maa,fi ati ti gbodo je oro-ise. LIT:Akojopo awon owe ti o jeyo lati inu iwe Asayan ewi ti ajo WAEC/NECO. if(typeof ez_ad_units != 'undefined'){ez_ad_units.push([[580,400],'edudelighttutors_com-medrectangle-3','ezslot_2',604,'0','0'])};__ez_fad_position('div-gpt-ad-edudelighttutors_com-medrectangle-3-0'); if(typeof ez_ad_units != 'undefined'){ez_ad_units.push([[336,280],'edudelighttutors_com-medrectangle-4','ezslot_5',605,'0','0'])};__ez_fad_position('div-gpt-ad-edudelighttutors_com-medrectangle-4-0'); Awon omo wo ni ape ni omo amutorunwa?Omo amutorunwa ni awon omo ti a bi ni ipase ami iyanu ona ti won gba waye yato si bi a ti bi omo orisirisi ona ni won gba waye. Ipin Kerin: Akanko Ede Ko Akanlo ede marun-un, ki o so itumo won. Ipa ti awon elesin, LIT:Ewi Alohun gege bi orison ironu Yoruba: Ofo, Ogede, Itan riro, o je mo aroko asariiyanjiyan, ijiroro lori ori-oro ti o je mo aroko asariiyanjiyan, kiko ilapa ero, ASA:Asa Isinku ni Ile Yoruba: Orisiirisii ona ti a n gba sin oku, oku omode, oku agba, itufo, itoju oku ati sisin oku agba sinu ile. 1st Term Ss3 Yoruba Scheme of Work and Note Oro wa di eni to fe ku pade eni ti yoo pa a iro ibon yii ko da awon ara adugbo duro rara, se ti a ba sun ewure kan ogiri o le bu ni je. Se akiyesi awon ona ede inu ayoka ati itumo won ni ibamu pelu bi onkowe se loo. Adewoyin S.Y (2014) Imo, Ede, Asa Ati Litireso fun ile Sekondiri Agba Corpromutt Publihers Nig Ltd Oju iwe 101-119. Oro ise Asoluwadabo : ni oro-ise ti oluwa ati abo le gbapo ara won.Eyi ni pe a le si oluwa ati abo ni ipo pada laisi iyato ninu gbolohun naa. Itunmo awon oro Kurani Alaponle ti o se gba ra lee ni ede Yoruba pelu ki kaa ati ti tuu pelu ohun. Idi niyi ti awon agba fi maa n se akiyesi ipo ti omo ba gba waye, Ipo ti ebi wa, esin idile baba ki won to fun omo ni oruko, Yoruba ni ile laawo ki a to so omo ni oruko. A ki i ko o bi aroko. 6. The child born after Idowu is called Idogbe (if male) and Alaba (if female). ORUKO AMUTORUNWA ATI ITUMO - Akedejesu Akewi bi eni je eko - Facebook The first born of the twins is called Tw, a shortened form of T-aiy-w . Aroko ajemo - isipaya abbl. Awon ohun elo ni a n pe ni eroja isomoloruko. m ni a fi n da pupo ninu awon onkaye Yoruba mo nigba ti a n fi (i) mo onkapo, Merin (mu erin)=4 Ikerin (iko erin)=4th, Marun-un (mu aarun=5 Ikarun-un (iko arun)=5th, Mesan-an (mu esan)=9 Ikesan (iko esan)=9th, Mewaa (mu ewa)=10 Ikewaa (iko ewa)=10th, Mokanla (mu okan-le-ewa)11 Ikokanla (Iko-okan-le-ewa)11th, Mejila (Mu-eji-le-ewa)12 Ikejila (iko-eji-le-ewa)=12th, Metala (mu-eta-le-ewa)13 Iketala (iko-eta-le-ewa)13th, Merinla (mu-erin-le-ewa)14 Ikerinla (iko-erin-le-ewa)14th.